ao ja omundun ewe iyalode mesan lona meta ti yio je 27 ao lo mesan kan pomo ose ao nu olo ao ikeji na be ao lo iketa na be ao fi ose kookan le kanin kanin ko kan oje meta ao bo eko elewe kan ninu ile iwe ao gbe sinu igba kekere kan ao fi epo pupa fo eko yi ninu ile iwe yi ao gbodo fomi fo o ao wa fi eko yi pa gbogbo ara wa lati eri dese ao wa duro lori ewe eko yi ao wa we kanin kain meteta yi taba we tan ao ko kainkain ati ewe yi da sinu kota tabi salanga ao lo sun,ale ni wiwe re o,baba jeko aadari jin ewe ni insha alah orowa yio dayo.
ao to sinu igo ito idaji lai soro si enikankan ao waju obi abata sinu re ao depa fun ojo meje toba dojo keje ao yo kuro ninu ito wa ao wa saa ti yoo gbe ao lo papo. Ao fun obinrin naa je . Obinrin naa lelo ise yin fun okunrin. Te ban gbo Nibi loma kusi...
What type of ewe iyalode
ReplyDeleteAdupe sir
ReplyDeleteEseun adupe sir.
ReplyDeleteAdupe oo
ReplyDelete