eku asin kan,egbo tude pupo,odidi atare kan,aojo papo,aolo kuna dada,aoro sinu igo kan,aobu die nibe aoteni ejiogbe. OHUN RE--- akekakaka 3x arinkakaka 3x ogbe ori iroko bu gaga 3x akekakaka loruko ti anpe ifa,arinkakaka loruko ti anpe esu odara,ogbe ori iroko bu gaga loruko ti anpe eyin iyami osoronga,eyin leran eku asin nise,ekukeku kii dena de eku asin,ekukeku tioba dena de eku asin jinni jinni a mun , ki jinnijinni mun ota mi tobafe dena demi,tude oooo wa tu gbogbo ide arami,ki ona la funmi,ejiogbe lo gbe ore emi --omo--adura---- aomafi fokomu tabi ki amafi oti lo lararo,gbogbo igba ti abafe lo ni aoma pe ohun re oooo.....ema gbiyanju lati mase awon ise yio-----walahi talahi tested confirm
Eseun sue
ReplyDelete