Ewe eyinbisowo, ewe aje sefunsefun, ewe atewogba, iyere, ao lo won po, ao fa sinu isasun tuntun, ao bu epo pupa ati iyo sinu re, ao fi igbin kan see je....
ao to sinu igo ito idaji lai soro si enikankan ao waju obi abata sinu re ao depa fun ojo meje toba dojo keje ao yo kuro ninu ito wa ao wa saa ti yoo gbe ao lo papo. Ao fun obinrin naa je . Obinrin naa lelo ise yin fun okunrin. Te ban gbo Nibi loma kusi...
Comments
Post a Comment