Ewe atewogba, ewe inabo, ewe orijin, iyere, ao lo won po, ao fa sinu isasun tuntun, ao fi se ori ewure lepo niyo, ao se jina daada, ao se lale, ao ji je lowuro kutu ojo keji, ao pe ofo re si ki a to je... Ofo re:- Ori kunkun ni ekeregbe fi nwo ile onile, gbogbo oun ti atewogba ba nawo si lo ngba, orijin loni ki gbogbo Omo araye wa maa fi ohun rere jinmi, oju oloko ni inabo se nbole... Adura...

Comments
Post a Comment