AO han Surah Isaja 41 ao fi omi foo dia sibikan ao wa lo afomo lapalapa funfun oojo die ao loo pelu Iyere die ao wa fise Kidirin maalu kanje ao gee kindinrin yi si mesan fun okun meje fun obinrin ao wa so lori itedi aso funfun ao je ao.Odaju saka lase olorun
ao to sinu igo ito idaji lai soro si enikankan ao waju obi abata sinu re ao depa fun ojo meje toba dojo keje ao yo kuro ninu ito wa ao wa saa ti yoo gbe ao lo papo. Ao fun obinrin naa je . Obinrin naa lelo ise yin fun okunrin. Te ban gbo Nibi loma kusi...
Comments
Post a Comment