Skip to main content

ASIRI NLA LORI IRAWO EDA

Lotito nipe irawo omin ati  ina koba arawon mu,gege bi awon alfa onifalaki mererin seso, alakoko abu masari Al falaki:::: elekeji seu muhemmed basmul::::: eleketa sheu jamiu bulala,:::::elerin sheu NASIRU al kabara,sugbon atunse siwa, idiniyi tofijepe awon tonlo osu oju orun nukan lolorun fi imon irawo si odo won,awon tonlo date of birth, won kanso awon eyan sinu okunkun lasan ni,,,ti eyan baje omin lapejuwe oko tabi iyawo ti enukan je ina awon mejeji won omase sara pupa gege bi akara elepo,tabi okaba pupa,__________{IRAWO AFEFE} awon irawo ti onsise musteri je irawo alalubarika ti amonsi برج الهوائية irawo afefe je number 3ninu awon irawo,tosijepe gbogbo eniti o abanlo ogbodo mase Sara afefe gege bi adire funfun agbon owo tabi aso funfun ati dudu,lati mako fun awon arugbo,sugbon opolopo komon ona abayo nitoripe awon oni ATROLORJY tiso olopopo awon eyan nu latara aikewu,elomin kogbo larubawa kotunmoka,awon ti won sisoro nipa irawo gbogbo won latoke dele,osu oju orun niwon nfiwo irawo,kokise date of birth,_________IRAWO OMIN_______awon onirawo omin gbodo mase Sara odo dada,toripe mujar manba irawo je ni, gege bi epose manba asoje,egbo oroti sheu basimulu so ninu tira re, المائية في طريقة النجومية،هي برج العالية التي يتمتع بها ومن كان صاحبها،فليتصدق البرية،,,, gbogbo onirawo omin gbodo mase Sara odo,ki osijina si inkan odo nijije,gegebi alakan ,ede,igbin,eja abori,ijapa,igbin,ati bebe lo,ti obasi fese sara aso funfun egusi sise,agbon,iyo,ki ose sinu aso funfun kolo gbesi odo tonsan,________AWON ONIRAWO IRUPE_______kigbogbo onirawo irupe sora lati fe afefe toripe olewu pupoju,ki osise iwadi dada komonjepe kosiru tidapo mon irawo re,inkan pupa bran loba iru irawo bemu,kosi jina si obirin pupa ni fife,ti kosiru badapo mon irawo gbogbo ogunti eniyan banse konisise,gege bi onirawo afefe,tabi ki eyan mala alakala,onje oju orun,biba obirin sun, promise and Vale,owu alantakun,ati bebelo,______AWON ONIRAWO INA_______gbogbo onirawo ina ogbodo koju isoro lashot,toripe irawo tomnbinu niwon ti ki SI fi asiri lo enikankan, agbalagba tonsare ninu ekan bi ole inkan inkan nle,,jowo sumon awon alfa onifalaki tomon nipa irawo lagbegbe re,ki Obama ma fi ogun ete pa lapalapa,, gbogbo oju ti oka post yi, Surat fatia kan funyin,ojuyin koniribi kosi nifo, الحمدلله رب العالمين الرحمن الرحيم مالك يوم الدين اياك نعبد واياك نستعين اهدنا الصراط المستقيم صراط الذين أنعمت عليهم غير المغضوب عليهم ولاضالين أمين،iseti olorun ran admin  lonje,ti obaka post yi,fi enu arare se adura sope,{ OLUWA MAFI OGOMI JEMI NIYA}

Comments

Popular posts from this blog

IFERAN AFUNJE OBINRIN TO LAGBARA

ao to sinu igo ito idaji lai soro si enikankan ao waju obi abata sinu re ao depa fun ojo meje toba dojo keje ao yo kuro ninu ito wa ao wa saa ti yoo gbe ao lo papo. Ao fun obinrin naa je . Obinrin naa lelo ise yin fun okunrin. Te ban gbo Nibi loma kusi...

ATUDE ASINA OWO KIAKIA

eku asin kan,egbo tude pupo,odidi atare kan,aojo papo,aolo kuna dada,aoro sinu igo kan,aobu die nibe aoteni ejiogbe. OHUN RE--- akekakaka 3x arinkakaka 3x ogbe ori iroko bu gaga 3x akekakaka loruko ti anpe ifa,arinkakaka loruko ti anpe esu odara,ogbe ori iroko bu gaga loruko ti anpe eyin iyami osoronga,eyin leran eku asin nise,ekukeku kii dena de eku asin,ekukeku tioba dena de eku asin jinni jinni a mun , ki jinnijinni mun ota mi tobafe dena demi,tude oooo wa tu gbogbo ide arami,ki ona la funmi,ejiogbe lo gbe ore emi --omo--adura---- aomafi fokomu tabi ki amafi oti lo lararo,gbogbo igba ti abafe lo ni aoma pe ohun re oooo.....ema gbiyanju lati mase awon ise yio-----walahi talahi tested confirm

ATUDE ASINA AFORIJIN AWON AGBA,

ao ja omundun ewe iyalode mesan lona meta ti yio je 27 ao lo mesan kan pomo ose ao nu olo ao ikeji na be ao lo iketa na be ao fi ose kookan le kanin kanin ko kan oje meta ao bo eko elewe kan ninu ile iwe ao gbe sinu igba kekere kan ao fi epo pupa fo eko yi ninu ile iwe yi ao gbodo fomi fo o ao wa fi eko yi pa gbogbo ara wa lati eri dese ao wa duro lori ewe eko yi ao wa we kanin kain meteta yi taba we tan ao ko kainkain ati ewe yi da sinu kota tabi salanga ao lo sun,ale ni wiwe re o,baba jeko aadari jin ewe ni insha alah orowa yio dayo.