Oga Gbigbe 4, opolo Gbigbe 4, asin Gbigbe 4, laderipon 4, ako epoobo, EPO igi nla, ewe orijin, ewe mafowokanomomi mejeji, akara ori akitan gbigbe, egbo tude, ewe ajeobale, aogun gbogbo won kunna dada, aopomose dudu pelu oronro malu ati eje olongbo toti ya ehanna, aoma we sun lalale ni pelu omi toloworo. Fun eni tikii base alabosi, o gbodo mu ope wa ni dandan

Please sir, what is Akara ori akitan?
ReplyDelete