Omi Inu agbon meta ewe Anu ewe aje ewe sawerepepe ewe ola iyere aolopo omi agbon yi laofilo ise yi naa okan malu kan Edo malu die ponmo sunsun die aowase lepo niyo katosetan alejo gbodo bawa nibe ti abase tan aolo te aso funfun kan sile ori re lajoko si pelu gbolohun
Ofo == eyin alasofunfun Nile alara3* eyin alasofunfun Nile alaje 3* eyin Egbe Aiye eyin Egbe orun ewalogbe owo totowo wa fun emi l OMO l loni tori awo Ara malu ni bo Asiri malu ategun ateran nibasiri Edo oshole ajele eparapo efowo NLA NLA sanumi kebomi lasiri billions loni ako aseje yi je kogbodo jasi ori asoyio aomafi asoyi sabe igberi wa odaju ebami danwo kia kia kefunle labo emi ni imam patako.

Comments
Post a Comment