Odindi ijapa, alakan kan, ewe abomoda 201,ao gun papo, ao sa gbe, ao joo(sieve), ao ro sinu igo, ao maa fi se edo maalu ti a ge si ona 16, ao maa fi epo ati iyo si... Ao ma se je pelu adua...
ao to sinu igo ito idaji lai soro si enikankan ao waju obi abata sinu re ao depa fun ojo meje toba dojo keje ao yo kuro ninu ito wa ao wa saa ti yoo gbe ao lo papo. Ao fun obinrin naa je . Obinrin naa lelo ise yin fun okunrin. Te ban gbo Nibi loma kusi...
Comments
Post a Comment