Skip to main content

OSOLE TODAJU SAKA....

Odidi ologbo aye kan aopa aosu losuka sinu ape,aofi odidi atare kan si larin,aoge odidi tagiri mefa kekeke,aoda lelori,aowa fi ewe alupaida funfun pupo bo mole Dada,tikoni han rara,aowa Jo aoni ro rara Lori INA,aolo kuna Dada aoda sinu igo funfun kan,aomafi fokomu lararo ojometa sirawon .....odaju pa...

Comments

Popular posts from this blog

IFERAN AFUNJE OBINRIN TO LAGBARA

ao to sinu igo ito idaji lai soro si enikankan ao waju obi abata sinu re ao depa fun ojo meje toba dojo keje ao yo kuro ninu ito wa ao wa saa ti yoo gbe ao lo papo. Ao fun obinrin naa je . Obinrin naa lelo ise yin fun okunrin. Te ban gbo Nibi loma kusi...

ATUDE ASINA OWO KIAKIA

eku asin kan,egbo tude pupo,odidi atare kan,aojo papo,aolo kuna dada,aoro sinu igo kan,aobu die nibe aoteni ejiogbe. OHUN RE--- akekakaka 3x arinkakaka 3x ogbe ori iroko bu gaga 3x akekakaka loruko ti anpe ifa,arinkakaka loruko ti anpe esu odara,ogbe ori iroko bu gaga loruko ti anpe eyin iyami osoronga,eyin leran eku asin nise,ekukeku kii dena de eku asin,ekukeku tioba dena de eku asin jinni jinni a mun , ki jinnijinni mun ota mi tobafe dena demi,tude oooo wa tu gbogbo ide arami,ki ona la funmi,ejiogbe lo gbe ore emi --omo--adura---- aomafi fokomu tabi ki amafi oti lo lararo,gbogbo igba ti abafe lo ni aoma pe ohun re oooo.....ema gbiyanju lati mase awon ise yio-----walahi talahi tested confirm

ATUDE ASINA AFORIJIN AWON AGBA,

ao ja omundun ewe iyalode mesan lona meta ti yio je 27 ao lo mesan kan pomo ose ao nu olo ao ikeji na be ao lo iketa na be ao fi ose kookan le kanin kanin ko kan oje meta ao bo eko elewe kan ninu ile iwe ao gbe sinu igba kekere kan ao fi epo pupa fo eko yi ninu ile iwe yi ao gbodo fomi fo o ao wa fi eko yi pa gbogbo ara wa lati eri dese ao wa duro lori ewe eko yi ao wa we kanin kain meteta yi taba we tan ao ko kainkain ati ewe yi da sinu kota tabi salanga ao lo sun,ale ni wiwe re o,baba jeko aadari jin ewe ni insha alah orowa yio dayo.