Lotito nipe irawo omin ati ina koba arawon mu,gege bi awon alfa onifalaki mererin seso, alakoko abu masari Al falaki:::: elekeji seu muhemmed basmul::::: eleketa sheu jamiu bulala,:::::elerin sheu NASIRU al kabara,sugbon atunse siwa, idiniyi tofijepe awon tonlo osu oju orun nukan lolorun fi imon irawo si odo won,awon tonlo date of birth, won kanso awon eyan sinu okunkun lasan ni,,,ti eyan baje omin lapejuwe oko tabi iyawo ti enukan je ina awon mejeji won omase sara pupa gege bi akara elepo,tabi okaba pupa,__________{IRAWO AFEFE} awon irawo ti onsise musteri je irawo alalubarika ti amonsi برج الهوائية irawo afefe je number 3ninu awon irawo,tosijepe gbogbo eniti o abanlo ogbodo mase Sara afefe gege bi adire funfun agbon owo tabi aso funfun ati dudu,lati mako fun awon arugbo,sugbon opolopo komon ona abayo nitoripe awon oni ATROLORJY tiso olopopo awon eyan nu latara aikewu,elomin kogbo larubawa kotunmoka,awon ti won sisoro nipa irawo gbogbo won latoke dele,osu oju orun niwon nfiwo ira...